[Music + Video] Fori Bale – Sundpraiz Ft. ZionSoar

Fori Bale - Sundpraiz Ft. ZionSoar

Nigerian gospel singer, worship leader and an entrepreneur Obadiah Sunday widely known as  ‘Sundpraiz‘ releases a new single titled ‘Fori Bale (Bow Down)‘. Produced By DeeJayBee

Fori Bale was written and composed by ‘Sundpraiz’ featuring Oyetunji Abiodun Sunday popular known as ‘Zionsoar‘.

Telegram

Stay Safe!! Stream & Download Audio Below; 

 

DOWNLOAD MUSIC

 

 

Lyrics: Fori Bale By Sundpraiz Ft. ZionSoar

Chorus
Mo fori Bale fun o oh Baba,
Mo fori Bale fun o oh baba (2×)

Verse 1
Odami loju,
Be kun pe dale Kan ayo nbo lowuro , bekun pe dale kan ayo nbo lowuro, ireti ojo pipe yen o tiwa pada bo dimuse ope ni mo mu wa o baba wa tewo gbope mi,
Iyin ni mo mu wa o baba wa tewo gba iyin mi
olore eeh, wa tewo gbope mi.

Chorus

Verse 2
Baba fun alaini baba, ogbigba to n gbomo orukan,
Yeye fun alaini yeye ogbigba to n gbomo orukan,
iwo ni lana ( yes )
iwoni loni ,
iwo ni lola lojo gbogbo,
iwo lo se yi
iwo lo se Yen
iwo lose toni o ma tun se t’ola,
iwo lo se yii
iwo lo se yen
iwo lo se toni oma tun se tola
ooh aah iwo ni……

Into…..

Verse 3
Mowa dupe lowo baba, Baba mo dupe o ( 2×)
Fun ore to se fun mi ati ebi ati ara mi gbogbo mo wa dupe lowo baba, baba mo dupe oo fun ore to se eeh …….

Chorus 2×

The post [Music + Video] Fori Bale – Sundpraiz Ft. ZionSoar appeared first on Gospel Songs.

Share on Google Plus

About Joy

0 Comments:

Post a Comment